NGA VS GUI: Super Eagles àti Syli National Guinea ṣẹ́ eegun ẹ̀yìn Guinea pẹ̀lú 1-0

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ikọ agbabọọlu ọkunrin fun orileede Naijiria Super Eagles, wọ iya ija pẹlu akẹgbẹ wọn, syli Nationale lati orileede Guinea.
Ifẹsẹwọnṣẹ yii ni ẹlẹkeeji ti wọn yoo gba ninu idije Afcon 2019, lẹyin ti wọn jawe olubori ninu ifẹsẹwọnsẹ wọn akọkọ pẹlu Burundi.
Kenneth Omeruo lo gba bọọlu kan ṣoṣo ti Naijiria fi bori sinu àwọ̀n nibi idije naa to waye ni papa iṣere Alexandria, nilu Alexandria.
Nibayii, Super Eagles ti bọ si ipele keji (Round of 16) idije Afcon 2019.
Nigeria
1
-
0
Guinea
Ere pari
Ẹkunrẹrẹ
Ilana ere bọọlu
Nigeria
(4-2-3-1)
Guinea
(4-2-3-1)
Ẹkunrẹrẹ
-
27-Falette0 - 0
-
62-Musa0 - 0
-
65-Seka0 - 0
-
71-Naby KeitaLass0 - 0
-
73-DyrestamSidibé0 - 0
-
73-Omeruo1 - 0
-
78-IwobiChukwueze1 - 0
-
82-KamanoKoita1 - 0
-
88-IghaloPaul Onuachu1 - 0
-
90-Peter Etebo1 - 0
-
94-SimonKalu1 - 0
Alaye ni soki lori ere bọọlu
Nigeria
Guinea
-
Bọọlu wa nikawọ mi48.2%51.8%
-
Gbigba bọọlu si oju ile43
-
Gba bọọlu108
-
kọna101
-
Ṣẹ sofin1312
Awọn agbabọọlu ti wọn yan
Awọn ti wọn o kọkọ bẹrẹ
Nigeria
-
16Akpeyi
-
22Omeruo
-
6Balogun
-
2Ola Aina
-
20Awaziem
-
4Wilfred Ndidi
-
7Musa
-
15Simon
-
8Peter Etebo
-
18Iwobi
-
9Ighalo
Guinea
-
12Koné
-
3Issiaga Sylla
-
18Dyrestam
-
5Seka
-
6Falette
-
10Kamano
-
13Cissé
-
4Diawara
-
16Traoré
-
8Naby Keita
-
21Kaba
Awọn iyipada
-
78IwobiChukwueze
-
88IghaloPaul Onuachu
-
94SimonKalu
-
71Naby KeitaLass
-
73DyrestamSidibé
-
82KamanoKoita
Awọn ti wọn paarọ
-
10Mikel
-
5Troost-Ekong
-
11Onyekuru
-
19Ogu
-
17Kalu
-
21Osimhen
-
23Uzoho
-
1Ezenwa
-
13Chukwueze
-
14Paul Onuachu
-
9Kanté
-
2Mohamed Yattara
-
7Mohamed Camara
-
23Fodé Camara
-
19Koita
-
11Idrissa Sylla
-
17Fofana
-
20Lass
-
1Naby-Moussa Yattara
-
14Sidibé
-
22Aly Keita
-
15Jeanvier




















