BBC News, Yorùbá - Ìròyìn
Ìròyìn tó ṣe kókó
Ipa wo ni ogun Amẹrika àti Israel sí Iran yóò ní lára Naijiiria?
Bo tilẹ jẹ pe ọpọ lo gbagbọ pe ogun yii ko kan awọn eeyan Afrika gbọngbọn, pupọ lara awọn ọmọ ilẹ Afrika to wa lawọn ilẹ ti ogun naa kan ni wọn ti n ha sọhun bayii.
Ìjoba Amẹrika kéde orúkọ àwọn ológun rẹ̀ tó ti bá ogun Iran lọ báyìí
Ọmọ ogun mẹfa lo jade laye lẹyin ti ado oloro kan ja lulẹ si ojuko ọmọ ogun Amẹrika to wa ni Port Shuaiba, lorilẹede Kuwait, lọjọ Aiku.
Èèmọ̀ ńlá ! Suleiman pa ẹ̀gbọ́n rẹ̀ nílùú Ṣẹ̀pẹ̀tẹ̀rí, Ó ní torípé ó yìnbọn fún òun lójú àlá
Nikete ti afurasi naa ṣe iṣẹ ibi ọhun tan lo na papa bora.
Èdè-àìyedè inú ìjọ Angilican bẹ́yìn yọ, àwọn àlùfáà tó tako ìyànsípò obìnrin gẹ́gẹ́ bí Bíṣọ́ọ̀bù Àgbà Canterbury tuntun, fẹ́ yan adarí míì
Igun Gafcon ninu ijọ Anglican ko ara wọn jọ nílùú Abuja lati Ọjọru ọsẹ yii pẹlu èròngbà láti yan adarí ijọ Anglican ti wọn.
El Mencho: Olórí agbóògùn olóró tí wọ́n fi pósí wúrà sin òkú rẹ̀ ní Mexico
El Mencho ni o padanu ẹmi rẹ lẹyin to farapa lasiko ti ija bẹ silẹ laarín awọn oluṣọ rẹ ati awọn ikọ ologun Mexico ti wọn ran lọ lati mu un ni iparí Oṣu Keji.
Àjọ ICPC kéde àwọn nǹkan tí wọ́n kó nílé El-Rufai l'Abuja, ẹbi El-Rufai ké gbàjarè
ICPC ṣalaye pe awọn ọlọpaa tẹle awọn oṣiṣẹ ajọ naa lọ si ile El-Rufai, ati pe iyawo rẹ gan an, Hadiza El-Rufai, ati ọmọkunrin rẹ, Muhammed El-Rufai, wa nile nigba ti ajọ ICPC lọ sile rẹ.
Àwọn olùjọsìn tí wọ́n jígbé nílé Ìjọsìn Cẹ̀lẹ́ n'ilu Uso gba ìtúsílẹ̀ lẹ́yìn òbítíbitì owó.
Awọn ẹbi awọn ti wọn jigbe naa sọ di mimọ pe wọn san Millionu mẹsan naira.
Àwọn agbébọn ṣekúpa àgbè, aráàlú faraya, ṣe ìfẹ̀hónúhàn ní Ondo
Awọn olugbe ogbese gbe paali pẹlu oniruru akọle si lara, bi wọn ṣe fi aidunu wọn han
Ọlọ́pàá bẹ̀rẹ̀ ìwádìí ìkú 'Obesere' olórí ọ̀dọ́ tí agbébọn jí gbé l'Ondo
Iṣẹlẹ ijinigbe bayii ti di tọrọfọnkalẹ nipinẹ Ondo, o si fẹ ẹ jọ bii pe gbogbo igba ni wọn n ji eeyan gbe nibẹ.
'A máa ba gbogbo àdó olóró wọn jẹ́, a máà sọ wọ́n di ẹdun arinlẹ̀' Trump ṣàlàyé ìdí tí Amẹ́ríkà àti Israel fi ń kọlu Iran
Amẹrika ati Israle kọlu Iran, amọ Iran naa ti bẹrẹ awọn akọlu si awọn orilẹede ti ọmọ ogun Israel wa.
Ìkọlù Amẹ́ríkà àti Israel sí Iran ti gbẹ̀mì Ayatollah Khamenei lẹ́yìn ọgbọ̀n ọdún lórí oyè; kí ni ipa rẹ̀ nínú ohun tó fa ogun náà?
Ọjọ kinni ti Amẹrika ati Israel bẹrẹ ikọli si Iran ni wọn gbẹmi Ayatollah Khamenei.
Àwa kọ́ la bẹ̀rẹ̀ ogun pẹ̀lú Iran, ṣùgbọ́n àwa la máà fòpin síi – Hegseth, alákóso ètò àbò nílẹ̀ Amẹ́ríkà
Ileeṣẹ alaabo orilẹede Israel tun sọ pe awọn ti kọlu ọkan lara awọn agba ọjẹ ẹgbẹ Hezbollah ni ilu Beirut.
Móríwú
BBC News Yorùbá ti wà lórí ìkànnì WhatsApp
Má jẹ́ kí etí rẹ ó di sí gbogbo ìròyìn ohun tó ń lọ ní Naijiria àti káàkiri àgbáyé. Mọ̀ nípa wọn lórí ìkànnì Whatsapp rẹ
Ìròyìn Àkàgbádùn
PDP kò tí ì kọ́gbọ́n rárá, ẹ̀yìn Tinubu ni mo ṣì wà fún 2027-Nyesom Wike
Wike sọ eyi nigba to n ba awọn akọroyin niluu Abuja
Ìròyìn tó sọ pé alásè kan fi májèlé sínú oúnjẹ́ fún Ààrẹ Tinubu; ohun tí a mọ̀ nìyí
Yatọ si atẹjade ileeṣẹ aarẹ yii, ko tii si ileeṣẹ aarẹ kankan to tii gbe iroyin jade lori rẹ
Akire tí ìlú Ikire ní ìpínlẹ̀ Osun, Ọba Olatunde Falabi wàjà
Ọdun mọkanlelaadọrun ni ori ade naa lo loke epẹ ki ori ade.
Agbébọn padà sí agbègbè Woro ní Kwara, gbẹ̀mí èèyàn, jí oúnjẹ, fóònù, àti nǹkan míì kó lọ
Lalẹ ọjọ Abamẹta, ọjọ kejidinlọgbọn, oṣu Keji yii ni iṣẹlẹ to sọ awọn araalu si siba-sibo yii waye.
Iran kéde Alireza Arafi gẹ́gẹ́ bí adelé olórí orílẹ̀ èdè lẹ́yìn ikú Ayatollah Ali Khamenei
Aarẹ Trump ni ikọlu si Iran yoo tẹsiwaju titi ti alaafia yoo fi jọba lẹkun Middle East ati ni gbogbo agbaye.
Ìjàmbá iná ṣọṣẹ́ ní òtẹ́ẹ̀lì àwọn olówò nàbì ní Ilorin, oníbàárà kan jóná mọ́lé
BBC News Yoruba kan si agbegbe ti iṣẹlẹ ijamba ina naa ti waye ti arakunrin kan to jẹ olugbe agbegbe naa ti a forukọ bo lasiri sọ pe bi ina ọba ṣe de mi ni otẹẹli naa bẹrẹ si n jo.
"Tí mi ò bá rí ògùn rà fún ọmọ mi, á máa gé ara rẹ̀ jẹ títí ẹ̀jẹ̀ yóò fi máa ṣàn"
Iya ọmọ ọhun ni ọpọlọpọ ilana ibilẹ ni wọn ti gba lati tọju rẹ ki awọn dokita to ri nkan to n ṣe e gangan.
Àwọn ajínigbé yìnbọn fún dẹ́rẹ́bà, jí èrò mẹ́fà gbé lọ ní Kogi
BBC News Yoruba kan si ọkan ninu awọn olugbe agbegbe ti iṣẹlẹ naa ti waye, arakunrin Olubasiri Babatunde, o si sọ ohun ti o mọ nipa rẹ.
Àjọ NSCDC kẹ́dùn ikú òṣìṣẹ́ rẹ̀ tí ọkọ̀ tẹ̀ pa l'Abuja
Agbẹnusọ ajọ naa, Babawale Afolabi sọ pe inu ajọ naa bajẹ gidigidi lori iku obinrin ọhun, ati pe iṣẹ ti bẹrẹ lati ṣeto isinku to dara fun.
Taiwo Adegbodu, olórin ẹ̀mí ẹgbẹ́ Adegbodu Twins jáde láyé
Ekeji rẹ, Kehinde Adegbodu lo fi ikede iku Taiwo lede lonii ọjọ Isinmi.
Nítorí aṣọ ilé ẹ̀kọ́, bàbá akẹ́kọ̀ọ́ lọ lu olùkọ́ lálùbolẹ̀ ni Kwara
Iroyin ni niṣoju awọn akẹkọọ ni ọgbẹni Adepoju Arewa ti lu olukọ naa ni alubami ti ọpọ eeyan si n ṣe kayefi lati mọ ohun to ṣẹlẹ to to bẹẹ.
Ẹ wọ́gilé ìsìn ìṣọ́ òru nítorí ètò àbò tó mẹ́hẹ – Ọlọ́pàá Ondo kìlọ̀ fáráàlú
Kọmiṣọna ọlọpaa ipinlẹ ọhun, Adebowale Lawal lo fi imọran naa lede lọjọ Ẹti niluu Akure lasiko to n ba awọn akọroyin sọrọ lori awọn ọmọ ijọ CCC mẹfa ti awọn agbebọn ji gbe nibẹ.
Ìròyìn Pàtàkì
Ẹ tẹ̀lé wa lórí ìkànnì ayélujára
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Àwọn agbébọn jí èèyàn mẹ́rin nínú ìdílé kan náà gbé ní Kwara
Isẹlẹ yii waye ni aarọ kutu ọjọ Ọjọru, ọjọ karunlelogun osu yii nibi ti wọn ti n roko.
Akọrin Fuji, Shanko Rasheed pàdánù àkọ́bí ọmọ rẹ̀, Jamal
Ní ìdájí kùtùkùtù ọjọ́ Ẹtì, ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ̀n, oṣù Kejì, ọdún 2026 ni ìṣẹ̀lẹ̀ láabi náà wáyé.
Àjọ INEC kéde ọjọ́ tuntun fún ìbò gómìnà ìpínlẹ̀ Osun, ètò ìdìbò Ààrẹ 2027
Ni akọkọ, Ogunjọ oṣu Keji ọdun 2027 ni ọjọ ti INEC mu eto idibo aarẹ ati ile igbimọ aṣofin agba , ti wọn si mu ọjọ kẹfaa oṣu Kẹta gẹgẹ ọjọ fun eto idibo fun eto idibo Gomina ati ile igbimọ aṣofin ipinlẹ.
Ohun tí ṣíṣe àtúntò iléeṣẹ́ ọlọ̀pàá túmọ̀ sí fún Nàìjíríà
Ìpè fún ìdásílẹ̀ àwọn ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ kò ṣẹ̀yìn bí ìkọlù àwọn agbébọn àti agbéṣùmọ̀mí, jíjí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbé, tó fi mọ́ àwọn ìpèníjà ààbò míì ṣe ń wáyé lemọ́lemọ́ káàkiri gbogbo orílẹ̀ èdè yìí.
Ọfà ni wọ́n ta mọ́ mí tó sọ mi di arọ, àwọn tó wà nídìí ọ̀rọ̀ mi kò jáwọ́ lẹ́yìn tí mo gbádùn tán - Ọ̀rọ̀ tí Okemesi sọ kó tó kú
Okemesi sọrọ yii ninu ifọrọwanilẹnuwo kan to ṣe lori itakun ayelujara pẹlu Jeff Owolewa.
Ọwọ́ tẹ afurasí olórí ikọ́ ISWAP tó lọ́wọ́ nínú ìkọlù sí ilé ìjọsìn Owo, l'Ondo
Afurasi naa, ni wọn pe orukọ rẹ ni Sani Yusuf, to si jẹ afurasi kẹfa ti ọwọ tẹ pe wọn ni nnkan ṣe pẹlu ikọlu to gba ẹmi ogoji eeyan, ti ọpọ si tun farapa.
Wo nǹkan tí Tunji Disu sọ lẹ́yìn tó gba ọ̀pá àṣẹ iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Naijiria
Disu ni asiko ko ti to fun ikini ku orire bayii nitori ẹru to wa ni ejika oun pọ lasiko yii, ti oun si ni lati bẹrẹ iṣẹ lẹsẹkẹsẹ.
Ẹ̀dà ìwé ìdájọ́ tó rán Ọba Ipetumodu lẹ́wọ̀n l'Amerika tẹ àwọn ìdílé ọba lọ́wọ́.
Tẹ ba gbagbe, ori ade yii, ẹni ọdun mejilelọgọta ni wọn gbe idajọ rẹ kalẹ ni ọjọ kẹrindinlọgbọ oṣu Kẹjọ ọdun 2025, pe o jẹbi ẹsun iwa ibaj
Afurasí mẹ́fà tó ń ṣe ayédèrú iṣẹ́ ìyanu kó sí gbaga ọlọ́pàá l'Ondo
Orukọ awọn afurasi naa ni Fadahunsi, Kolade, Tijani, Iyanuoluwa, Arijesulola ati Ademola.
Kí ló dé tí ẹnu ń kun Seyi Makinde àti Gómìná ìpínlẹ̀ Kano tẹ́lẹ̀ Rabiu Kwankwaso lórí ìpàdé bòńkẹ́lẹ́ tí wọ́n ṣe nílùú Ibadan?
Kwankwaso ati Seyi Makinde ni wọn dijọ wọ yara ipade Executive Chamber ti Ijọba Ipinlẹ Oyo ti wọn si ṣe ipade alatimori eyi to leeni ogoji isẹju.













































































