Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ bí Afcon Round of 16 yóò ṣe lọ

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ipele ẹlẹgbẹjẹgbẹ fun idije AFCON 2023 ti wa sopin bayii lẹyin ti wọn pari gbogbo ifẹsẹwọnsẹ to wa ni isọri naa.
Ọpọlọpọ ohun iyalẹnu lo ti ipele yii jade, paapaa bi awọn orilẹede alagbara ṣe ṣubu niwaju awọn orilẹede kan ti wọn ko fi bẹ lorukọ ti a ba n sọrọ ere boolu.
Lẹyin gbogbo ifẹsẹwọnsẹ ẹlẹgbẹjẹgbẹ naa, awọn orilẹede kan ni wọn ti fọwọ osi juwe fun, ti awọn mii si ni anfaani lati kopa ninu ipele ẹlẹni mẹrindinlogun nitori atunse tuntun ti ẹgbẹ CAF gbe kalẹ.
Eyi lo fa ti awọn orilẹede kan bi Cote di Ivoire to gba alejo idije naa, Guinea, Mauritania ati Namibia ti wọn gbe ipo kẹta ninu isọri wọn naa fi ni anfaani lati wọ ipele Round of 16.
Awọn orilẹede mẹrin yii ni wọn sapejuwe gẹgẹ bi awọn orilẹede to lulẹ sugbọn ti wọn si gbiyanju.
CAF lo iye ami ti ẹgbẹ agbaboolu gba ni isọri wọn ati bi wọn se fakọyọ ninu ifẹsẹwọnsẹ ti wọn kopa.
Awọn orilẹede to de ipele ẹni mẹrindinlogun 'Round of 16' re e
- Equatorial Guinea
- Nigeria
- Cape Verde
- Egypt
- Senegal
- Cameroon
- Guinea
- Angola
- Burkina Faso
- Mauritania
- Namibia
- DR Congo
- Ivory Coast
- South Africa
- Morocco
- Mali
Awọn esi ati bi Afcon 2023 group stage ṣe lọ
Idije ife-ẹyẹ ilẹ Africa fun ọdun 2023
- P - Ti wọn ti gba
- W - Eyi ti wọn ti jawe olubori
- L - Eyi ti wọn padanu
- D - Eyi ti wọn ti ta ọmi
- GD - Iyatọ laarin goolu ti wọn gba wọle
- Pts - Ami ayo
-
-
Ipin A
Orilẹede P W L D GD Pts Equatorial Guinea 3 2 0 1 6 7 Nigeria 3 2 0 1 2 7 Ivory coast 3 1 2 0 -3 3 Guinea Bissau 3 0 3 0 -5 0 -
13/01/2024, 20:00Ivory coast 2-0 Guinea Bissau-(Pẹnariti)(Papa iṣere Allassane Ouattara)
-
14/01/2024, 14:00Nigeria 1-1 Equatorial Guinea-(Pẹnariti)(Papa iṣere Allassane Ouattara)
-
18/01/2024, 14:00Equatorial Guinea 4-2 Guinea Bissau-(Pẹnariti)(Papa iṣere Allassane Ouattara)
-
18/01/2024, 17:00Ivory coast 0-1 Nigeria-(Pẹnariti)(Papa iṣere Allassane Ouattara)
-
22/01/2024, 17:00Equatorial Guinea 4-0 Ivory coast-(Pẹnariti)(Papa iṣere Allassane Ouattara)
-
22/01/2024, 17:00Guinea Bissau 0-1 Nigeria-(Pẹnariti)(Felix Houphouet-Boigny)
-
-
Ipin B
Orilẹede P W L D GD Pts Cape Verde 3 2 0 1 4 7 Egypt 3 0 0 3 0 3 Ghana 3 0 1 2 -1 2 Mozambique 3 0 1 2 -3 2 -
14/01/2024, 17:00Egypt 2-2 Mozambique-(Pẹnariti)(Felix Houphouet-Boigny)
-
14/01/2024, 20:00Ghana 1-2 Cape Verde-(Pẹnariti)(Felix Houphouet-Boigny)
-
18/01/2024, 20:00Egypt 2-2 Ghana-(Pẹnariti)(Felix Houphouet-Boigny)
-
19/01/2024, 14:00Cape Verde 3-0 Mozambique-(Pẹnariti)(Felix Houphouet-Boigny)
-
22/01/2024, 20:00Cape Verde 2-2 Egypt-(Pẹnariti)(Felix Houphouet-Boigny)
-
22/01/2024, 20:00Mozambique 2-2 Ghana-(Pẹnariti)(Papa iṣere Allassane Ouattara)
-
-
-
-
Ipin C
Orilẹede P W L D GD Pts Senegal 3 3 0 0 7 9 Cameroon 3 1 1 1 -1 4 Guinea 3 1 1 1 -1 4 Gambia 3 0 3 0 -5 0 -
15/01/2024, 14:00Senegal 3-0 Gambia-(Pẹnariti)(Papa iṣere Charles Konan Banny de Yamoussoukro)
-
15/01/2024, 17:00Cameroon 1-1 Guinea-(Pẹnariti)(Papa iṣere Charles Konan Banny de Yamoussoukro)
-
19/01/2024, 17:00Senegal 3-1 Cameroon-(Pẹnariti)(Papa iṣere Charles Konan Banny de Yamoussoukro)
-
19/01/2024, 20:00Guinea 1-0 Gambia-(Pẹnariti)(Papa iṣere Charles Konan Banny de Yamoussoukro)
-
23/01/2024, 17:00Gambia 2-3 Cameroon-(Pẹnariti)(Papa iṣere Bouake)
-
23/01/2024, 17:00Guinea 0-2 Senegal-(Pẹnariti)(Papa iṣere Charles Konan Banny de Yamoussoukro)
-
-
Ipin D
Orilẹede P W L D GD Pts Angola 3 2 0 1 3 7 Burkina faso 3 1 1 1 -1 4 Mauritania 3 1 2 0 -1 3 Algeria 3 0 1 2 -1 2 -
15/01/2024, 20:00Algeria 1-1 Angola-(Pẹnariti)(Papa iṣere Bouake)
-
16/01/2024, 14:00Burkina faso 1-0 Mauritania-(Pẹnariti)(Papa iṣere Bouake)
-
20/01/2024, 14:00Algeria 2-2 Burkina faso-(Pẹnariti)(Papa iṣere Bouake)
-
20/01/2024, 17:00Mauritania 2-3 Angola-(Pẹnariti)(Papa iṣere Bouake)
-
23/01/2024, 20:00Angola 2-0 Burkina faso-(Pẹnariti)(Papa iṣere Charles Konan Banny de Yamoussoukro)
-
23/01/2024, 20:00Mauritania 1-0 Algeria-(Pẹnariti)(Papa iṣere Bouake)
-
-
-
-
Ipin E
Orilẹede P W L D GD Pts Mali 3 1 0 2 2 5 South Africa 3 1 1 1 2 4 Namibia 3 1 1 1 -3 4 Tunisia 3 0 1 2 -1 2 -
16/01/2024, 17:00Tunisia 0-1 Namibia-(Pẹnariti)(Papa iṣere Amadou Gon Coulibaly)
-
16/01/2024, 20:00Mali 2-0 South Africa-(Pẹnariti)(Papa iṣere Amadou Gon Coulibaly)
-
20/01/2024, 20:00Tunisia 1-1 Mali-(Pẹnariti)(Papa iṣere Amadou Gon Coulibaly)
-
21/01/2024, 20:00South Africa 4-0 Namibia-(Pẹnariti)(Papa iṣere Amadou Gon Coulibaly)
-
24/01/2024, 17:00Namibia 0-0 Mali-(Pẹnariti)(Papa iṣere Laurent Pokou)
-
24/01/2024, 17:00South Africa 0-0 Tunisia-(Pẹnariti)(Papa iṣere Amadou Gon Coulibaly)
-
-
Ipin F
Orilẹede P W L D GD Pts Morocco 3 2 0 1 4 7 DR Congo 3 0 0 3 0 3 Zambia 3 0 1 2 -1 2 Tanzania 3 0 1 2 -3 2 -
17/01/2024, 17:00Morocco 3-0 Tanzania-(Pẹnariti)(Papa iṣere Laurent Pokou)
-
17/01/2024, 20:00DR Congo 1-1 Zambia-(Pẹnariti)(Papa iṣere Laurent Pokou)
-
21/01/2024, 14:00Morocco 1-1 DR Congo-(Pẹnariti)(Papa iṣere Laurent Pokou)
-
21/01/2024, 17:00Zambia 1-1 Tanzania-(Pẹnariti)(Papa iṣere Laurent Pokou)
-
24/01/2024, 20:00Tanzania 0-0 DR Congo-(Pẹnariti)(Papa iṣere Amadou Gon Coulibaly)
-
24/01/2024, 20:00Zambia 0-1 Morocco-(Pẹnariti)(Papa iṣere Laurent Pokou)
-
-
-
Ipele ẹlẹni mẹrindinlogun
-
27/01/2024, 17:00Angola 3-0 Namibia-(Pẹnariti)(Papa iṣere Bouake)
-
27/01/2024, 20:00Nigeria 2-0 Cameroon-(Pẹnariti)(Felix Houphouet-Boigny)
-
28/01/2024, 17:00Equatorial Guinea 0-1 Guinea-(Pẹnariti)(Papa iṣere Allassane Ouattara)
-
28/01/2024, 20:00Egypt 1-1 DR Congo7-8(Pẹnariti)(Papa iṣere Laurent Pokou)
-
29/01/2024, 17:00Cape Verde 1-0 Mauritania-(Pẹnariti)(Felix Houphouet-Boigny)
-
29/01/2024, 20:00Senegal 1-1 Ivory coast4-5(Pẹnariti)(Papa iṣere Charles Konan Banny de Yamoussoukro)
-
30/01/2024, 17:00Mali 2-1 Burkina faso-(Pẹnariti)(Papa iṣere Amadou Gon Coulibaly)
-
30/01/2024, 20:00Morocco 0-2 South Africa-(Pẹnariti)(Papa iṣere Laurent Pokou)
-
-
Ipele keji si aṣekagba
-
02/02/2024, 17:00Nigeria 1-0 Angola-(Pẹnariti)(Felix Houphouet-Boigny)
-
02/02/2024, 20:00DR Congo 3-1 Guinea-(Pẹnariti)(Papa iṣere Allassane Ouattara)
-
03/02/2024, 17:00Mali 1-2 Ivory coast-(Pẹnariti)(Papa iṣere Bouake)
-
03/02/2024, 20:00Cape Verde 0-0 South Africa1-2(Pẹnariti)(Papa iṣere Charles Konan Banny de Yamoussoukro)
-
-
Ipele to kẹyin si aṣekagba
-
07/02/2024, 17:00Nigeria 1-1 South Africa4-2(Pẹnariti)(Papa iṣere Bouake)
-
07/02/2024, 20:00Ivory coast 1-0 DR Congo-(Pẹnariti)(Papa iṣere Allassane Ouattara)
-
-
Ipo kẹta ati ipo kẹrin
-
10/02/2024, 20:00South Africa 0-0 DR Congo6-5(Pẹnariti)(Felix Houphouet-Boigny)
-
-
Aṣekagba
-
11/02/2024, 20:00Nigeria 1-2 Ivory coast-(Pẹnariti)(Papa iṣere Allassane Ouattara)
-
Bi awọn ifẹsẹwọnsẹ Round of 16 yoo ṣe lọ
Ọjọ Abamẹta si ọjọ Iṣẹgun ọsẹ to n bọ ni ipele Afcon Round of 16 yoo bẹeẹ. Orilẹ-ede Naijiria ati Cameroon si ni yoo kọkọ pade.
Ẹ wo eto bii awọn ifẹsẹwọnsẹ yoo ṣe lọ:
Nigeria vs Cameroon - 27 January ni Felix Houphouet Boigny Stadium in Abidjan
Angola vs Namibia - 27 January ni Stade de la paix in Bouake
Equatorial Guinea vs Guinea - 28 January ni Alassane Ouattara Stadium
Egypt vs DR Congo - 28 January ni Laurent Pokou Stadium.
Cape Verde vs Mauritânia - 29 January ni Felix Houphouet Boigny Stadium.
Senegal vs Ivory Coast - 29 January ni Charles Konan Banny Stadium.
Mali vs Burkina Faso - 29 January ni Amadou Gon Coulibaly Stadium.
Morocco vs South Africa - 30 January 30 ni Laurent Pokou Stadium.



























