Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn, èsì, iye góòlù àti ipò tí ikọ̀ agbábọ́ọ́lù kọ̀ọ̀kan wà nínú ìdíje Afcon 2025

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Ní báyìí, idije ife ẹyẹ láàrin àwọn orílẹ̀èdè nílẹ̀ Áfíríkà, tí a mọ̀ sí Afcon 2025 tí bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹu.
Afcon 2025 náà sì ni yóò máa wáyé laarin ọjọ́ kokanlelogun oṣù Kejìlá ọdún 2025 si ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kinni odun 2025.
Orílẹ̀èdè Morocco sì ni idije náà yóò ti máa wáyé.
Orílẹ̀ èdè Morocco náà sì ni yóò side ifesewonse níbi idije Afcon 2025 náà nítorí òun ló ń gbalejo idije ọhun.
Gbajúmọ̀ agbábọ́ọ́lù láti Morocco, Achraf Hakimi yóò sì wà lára àwọn agbábọ́ọ́lù tí yóò kopa ninu ifesewonse àkọ́kọ́.
Orílẹ̀ èdè Senegal, Ivory Coast, Egypt áti Nàìjíríà tí Victor Osimhen ń léwájú rẹ náà wà lára àwọn alátakò fún ikọ̀ agbábọ́ọ́lù orílẹ̀èdè Morocco nínú ìdíje Afcon 2025.
Idije ife-ẹyẹ ilẹ Africa fun ọdun 2025
Awọn ifẹsẹwọnsẹ ati esi wọn
Ipele ẹlẹgbẹjẹgbẹ
Ipin
- P - Ti wọn ti gba
- W - Eyi ti wọn ti jawe olubori
- L - Eyi ti wọn padanu
- D - Eyi ti wọn ti ta ọmi
- GD - Iyatọ laarin goolu ti wọn gba wọle
- Pts - Ami ayo
-
-
Ipin A
Orilẹede P W L D GD Pts Morocco 3 2 0 1 5 7 Mali 3 0 0 3 0 3 Comoros 3 0 1 2 -2 2 Zambia 3 0 1 2 -3 2 -
21/12/2025, 19:00Morocco 2-0 Comoros-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Prince Moulay Abdallah)
-
22/12/2025, 14:00Mali 1-1 Zambia-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Mohamed V)
-
26/12/2025, 17:30Zambia 0-0 Comoros-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Mohamed V)
-
26/12/2025, 20:00Morocco 1-1 Mali-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Prince Moulay Abdallah)
-
29/12/2025, 19:00Comoros 0-0 Mali-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Mohamed V)
-
29/12/2025, 19:00Zambia 0-3 Morocco-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Prince Moulay Abdallah)
-
-
Ipin B
Orilẹede P W L D GD Pts Egypt 3 2 0 1 2 7 South Africa 3 2 1 0 1 6 Angola 3 0 1 2 -1 2 Zimbabwe 3 0 2 1 -2 1 -
22/12/2025, 17:00South Africa 2-1 Angola-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade de Marrakech)
-
22/12/2025, 20:00Egypt 2-1 Zimbabwe-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade d'Agadir)
-
26/12/2025, 12:30Angola 1-1 Zimbabwe-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade de Marrakech)
-
26/12/2025, 15:00Egypt 1-0 South Africa-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade d'Agadir)
-
29/12/2025, 16:00Angola 0-0 Egypt-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade d'Agadir)
-
29/12/2025, 16:00Zimbabwe 2-3 South Africa-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade de Marrakech)
-
-
-
-
Ipin C
Orilẹede P W L D GD Pts Naijiria 3 3 0 0 4 9 Tunisia 3 1 1 1 1 4 Tanzania 3 0 1 2 -1 2 Uganda 3 0 2 1 -4 1 -
23/12/2025, 17:30Naijiria 2-1 Tanzania-(Pẹnariti)(Papa iṣire Complexe Sportif de Fès)
-
23/12/2025, 20:00Tunisia 3-1 Uganda-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Olympique de Rabat)
-
27/12/2025, 17:30Uganda 1-1 Tanzania-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade El Barid)
-
27/12/2025, 20:00Naijiria 3-2 Tunisia-(Pẹnariti)(Papa iṣire Complexe Sportif de Fès)
-
30/12/2025, 16:00Tanzania 1-1 Tunisia-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Olympique de Rabat)
-
30/12/2025, 16:00Uganda 1-3 Naijiria-(Pẹnariti)(Papa iṣire Complexe Sportif de Fès)
-
-
Ipin D
Orilẹede P W L D GD Pts Senẹgal 3 2 0 1 6 7 DR Congo 3 2 0 1 4 7 Benin 3 1 2 0 -3 3 Botswana 3 0 3 0 -7 0 -
23/12/2025, 12:30DR Congo 1-0 Benin-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade El Barid)
-
23/12/2025, 15:00Senẹgal 3-0 Botswana-(Pẹnariti)(Papa iṣire Grand Stade de Tanger)
-
27/12/2025, 12:30Benin 1-0 Botswana-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Olympique de Rabat)
-
27/12/2025, 15:00Senẹgal 1-1 DR Congo-(Pẹnariti)(Papa iṣire Grand Stade de Tanger)
-
30/12/2025, 19:00Benin 0-3 Senẹgal-(Pẹnariti)(Papa iṣire Grand Stade de Tanger)
-
30/12/2025, 19:00Botswana 0-3 DR Congo-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade El Barid)
-
-
-
-
Ipin E
Orilẹede P W L D GD Pts Algeria 3 3 0 0 6 9 Burkina Faso 3 2 1 0 2 6 Sudan 3 1 2 0 -4 3 Equitorial Guinea 3 0 3 0 -4 0 -
24/12/2025, 12:30Burkina Faso 2-1 Equitorial Guinea-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Mohamed V)
-
24/12/2025, 15:00Algeria 3-0 Sudan-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Prince Moulay El Hassan)
-
28/12/2025, 15:00Equitorial Guinea 0-1 Sudan-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Mohamed V)
-
28/12/2025, 17:30Algeria 1-0 Burkina Faso-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Prince Moulay El Hassan)
-
31/12/2025, 16:00Equitorial Guinea 1-3 Algeria-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Prince Moulay El Hassan)
-
31/12/2025, 16:00Sudan 0-2 Burkina Faso-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Mohamed V)
-
-
Ipin F
Orilẹede P W L D GD Pts Ivory Coast 3 2 0 1 2 7 Cameroun 3 2 0 1 2 7 Mozambique 3 1 2 0 -1 3 Gabon 3 0 3 0 -3 0 -
24/12/2025, 17:30Ivory Coast 1-0 Mozambique-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade de Marrakech)
-
24/12/2025, 20:00Cameroun 1-0 Gabon-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade d'Agadir)
-
28/12/2025, 12:30Gabon 2-3 Mozambique-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade d'Agadir)
-
28/12/2025, 20:00Ivory Coast 1-1 Cameroun-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade de Marrakech)
-
31/12/2025, 19:00Gabon 2-3 Ivory Coast-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade de Marrakech)
-
31/12/2025, 19:00Mozambique 1-2 Cameroun-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade d'Agadir)
-
-
Ipele komẹsẹoyọ
-
Ipele ẹlẹni mẹrindinlogun
-
03/01/2026, 16:00Senẹgal 3-1 Sudan-(Pẹnariti)(Papa iṣire Grand Stade de Tanger)
-
03/01/2026, 19:00Mali 1-1 Tunisia-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Mohamed V)
-
04/01/2026, 16:00Morocco 1-0 Tanzania-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Prince Moulay Abdallah)
-
04/01/2026, 19:00South Africa 1-2 Cameroun-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade El Barid)
-
05/01/2026, 16:00Egypt 3-1 Benin-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade d'Agadir)
-
05/01/2026, 19:00Naijiria 4-0 Mozambique-(Pẹnariti)(Papa iṣire Complexe Sportif de Fès)
-
06/01/2026, 16:00Algeria 1-0 DR Congo-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Prince Moulay El Hassan)
-
06/01/2026, 19:00Ivory Coast 3-0 Burkina Faso-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade de Marrakech)
-
-
Ipele keji si aṣekagba
-
09/01/2026, 16:00Mali 0-1 Senẹgal-(Pẹnariti)(Papa iṣire Grand Stade de Tanger)
-
09/01/2026, 19:00Cameroun 0-2 Morocco-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Prince Moulay Abdallah)
-
10/01/2026, 16:00Algeria 0-2 Naijiria-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade de Marrakech)
-
10/01/2026, 19:00Egypt 3-2 Ivory Coast-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade d'Agadir)
-
-
Ipele to kẹyin si aṣekagba
-
14/01/2026, 17:00Senẹgal 1-0 Egypt-(Pẹnariti)(Papa iṣire Grand Stade de Tanger)
-
14/01/2026, 20:00Naijiria 0-0 Morocco-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Prince Moulay Abdallah)
-
-
Ipo kẹta ati ipo kẹrin
-
17/01/2026, 16:00Egypt 0-0 Naijiria-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Mohamed V)
-
-
Aṣekagba
-
18/01/2026, 19:00Senẹgal 1-0 Morocco-(Pẹnariti)(Papa iṣire Stade Prince Moulay Abdallah)
-
Akoko ati agogo ilẹ Gẹẹsi la fi ṣeto rẹ, o silè yipada, BBC ko lagbara lori irufẹ ayipada bẹẹ.




















