BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Itan
5:04
Fídíò,
"Sodeke lá àlá pé wọ́n bímọ̀ tó rìn lóòjọ́, Ifá ní ẹ̀sìn àjèjì tí yòó sọ ilẹ̀ Ẹgba di ọ̀làjú ń bọ̀, ló fi gba ẹ̀sìn Krìsítẹ́nì"
, Duration 5,04
29 Agẹmo 2025
Àwọn egúngún mánigbàgbé nínú àṣà àti ìṣẹ̀ṣe ilẹ̀ Ibadan
20 Agẹmo 2025
5:40
Fídíò,
Ejigbo, ìlú ti gbogbo ìdílé ti n sọ èdè Faranse bótilẹ̀ jẹ́ pé ọmọ Yorùbá ni wọ́n
, Duration 5,40
15 Agẹmo 2025
Wo àwọn ọba ilẹ̀ Yorùbá tó lo, ó kéré tán àádọ́ta ọdún lórí ìtẹ́
15 Agẹmo 2025
Jesu Oyingbo rèé, pásítọ̀ tó láṣẹ ìbálòpọ̀ lórí ọmọ ìjọ obìnrin
13 Agẹmo 2025
Mọ̀ nípa Yèyémòlú, ìyàwó Odùduwà tó di omi tí gbogbo Ooni Ile-Ife ń mu
22 Òkùdu 2025
Oba Yesufu Oloyede Asanike: Olubadan tó gbóyà, aláwàdà àti Olubadan tó fi èèyàn joyè jùlọ láì fi ẹ̀yà ṣe
15 Òkùdu 2025
4:36
Fídíò,
Esie: ibùdó ìkónkan ìṣẹ̀mbáyé sí, níbi tí àwọn ère tí wọ́n bá jí kó ti ń fúnra wọn padà wálé
, Duration 4,36
10 Òkùdu 2025
Mọ̀ nípa rọ́bà ìdáàbò bò tó ti pé igba ọdún tí wọ́n ṣàfihàn rẹ̀ nílé ìkó nǹkan ìṣẹ̀mbáyé sí
6 Òkùdu 2025
Balogun Kuku: Akọni to mú Islam wọ ilẹ̀ Ijebu, bẹ̀rẹ̀ ọdún ojúde ọba, aya 65 tó ní kò jẹ́ kó gba ẹ̀sìn Kristẹni
5 Òkùdu 2025
Ìtàn ayé Baṣọ̀run Gáà, ìjòyè tó yan ọba mẹ́rin, tó sì pa ọba mẹ́rẹ̀ẹ̀rin àmọ́ ọba karùn-ún ló pa á
1 Òkùdu 2025
Ìtàn ayé Orúgbó, ìyá àgbà tó dá ìlú Omu-Aran sílẹ̀ ní 13th Century àmọ̀ tí wọn ‘ló wa láyé di òní’
30 Èbibi 2025
Ìtàn bí egúngún ṣe di àṣà nílùú Omu-Aran
20 Èbibi 2025
Ǹjẹ́ ẹ ti gbọ́ nípa ìlú Ugbo nípìnlẹ̀ Ondo, níbi tó ti jẹ́ èèwọ̀ láti fẹ́ obìnrin pupa?
11 Èbibi 2025
8:05
Fídíò,
Njẹ́ ẹ ti gbọ́ nípa Owu-Kuta nípìnlẹ̀ Osun, níbi tó ti jẹ́ èèwọ̀ láti ta iyán àti ẹ̀pà
, Duration 8,05
9 Ìgbé 2025
Ajayi Crowther ní ọjọ́ ìbànújẹ́ àmọ́ tó di ọjọ́ ayọ̀ ni ọjọ́ tí wọ́n kó òun lẹ́rú
6 Ìgbé 2025
3:59
Fídíò,
Ibí yìí ni Ọya wọlẹ̀ sí nílùú Ira, ìpínlẹ̀ Kwara, àti ìdí gan-an tó fi bínú wọlẹ̀
, Duration 3,59
11 Ẹrẹ̀nà 2025
Seriki Williams Abass: Ọba Badagry tó jẹ́ ẹrú, tó tún padà di olówò ẹrú
9 Ẹrẹ̀nà 2025
Ọọ̀ni obìnrin, Lúwòó Gbàgídà rèé, akọni tó ń gun ọkùnrin ní ẹṣin rìn
9 Ẹrẹ̀nà 2025
Àwọn nǹkan mẹ́wàá tó yẹ kí o mọ̀ nípa àgbà ẹgbẹ́ Afenifere, Pa Ayo Adebanjo tó jáde láyé
14 Èrèlè 2025
Ka bí àwọn ọmọ ogun Nazi ṣe pa èèyàn 1.2m lọ́gbà ẹ̀wọ̀n
28 Sẹ́rẹ́ 2025
Alábàṣiṣẹ́ Mukaila Ṣẹnwẹlẹ ṣàlàyé ohun tó ṣe kẹ́yìn kó tó jáde láyé
25 Sẹ́rẹ́ 2025
Nǹkan tó yẹ kóo mọ̀ nípa ọdún Oshoosi ní Ile Ife
19 Sẹ́rẹ́ 2025
Ìtàn Mánigbàgbé: Bode Thomas, ọpọlọ pípé, aṣaájú àmọ́ tó ní inú fùfù
17 Sẹ́rẹ́ 2025
Ìṣájú
Page
2
nínú
9
1
2
3
4
5
6
7
8
9
Tókàn