Man United vs Liverpool: Liverpool faṣọ iyì ya mọ́ Ole, Ronaldo àti Man U lára
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Liverpool ṣe ẹgbẹ agbaboolu Manchester United risa-risa ninu Ifẹsẹwọnsẹ idije Premier League to waye ni papa isere Old Trafford lọjọ Aiku.
Àmì ayo marun ùn sodo ni Liverpool gba si awọn Man U nile wọn eleyii ti United ko sí lee ta putu.
Ẹlẹsẹ ayo n ni, Mohammed Salah lo gbayo mẹta ọtẹtọ wọlé fun Liverpool ninu ere bọọlu ọhún.
Naby Keita lo kökọ ṣide ayo nigba ti o gba góòlù akọkọ s'awọn Man United.
Diogo Jota lo fi ọba lee fun Liverpool ni Old Trafford.
Lẹyin naa ni agbaojẹ Salah gba góòlù mẹta lera s'awọn
Ìròyìn tó ṣe kókó
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ
Content is not available
{{rankTranslation}}